L’ede Wa

Okan ninu ohun ti mo fe gbiyanju lati se ni kiko awon itan mi ni ede Yoruba. Eyi ma komi lati ranti ipa nla ti ede ko ni igbe aye wa. Bi o tilejepe, ni aye ode one, opo eko ti a ko ni ile iwe lo je ni ede oyinbo, sibesibe iwulo ede wa ko see fi owo gba si apa kan.

O da mi loju pe ti mo ba te are mo ati maa ko ede wa lojoojumo, yio mo mi lara lati te siwaju.

Loni mo fe ko nipa orin ewi ti a ma n ko nigba ti mo wa lewe:

Irawo

7973488-the-night-sky-in-stars-and-blue-galaxies

Mo ri kini kan loju orun

To ba dale a tan yoyoo

Kini a ti n pe kini naa?

Irawa to too to, irawo

Iru iyanu ki wa leyii

Lati mo bi o se n tan

O n dan yinrin, yinrin, o n danCategories: Education

Tags: ,

Please leave comments

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s

%d bloggers like this: